Listen to Olopa (feat. Zlatan) by Qdot

Olopa (feat. Zlatan)

Qdot

World

14,417 Shazams

Music Video

Featured In

Lyrics

(Yeah) Ìbílẹ' (Yeah) kapaichumarimarichopaco (Qdot lórúkọ mi) Alagbe, jẹ ọ mọ Ṣo ńgbọ? Ko sodi mare, wèrè loku (yepa) (Gun òkè) wọn ká pátá lọ tokun-tokun (ẹ da'gbo rú, jọọ) Ẹ p'ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá) Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier) Ẹ lọ pé EFCC, tó bá dé'bi, à jọ má ṣáyé pọ Ayé toto (ayé toto) Ayé akamara (ah, ayé akamara) iPhone lo ko'wo le, ọmọ ase, fufu lo ra (hello ẹ) Ẹ dàkún, ẹ gbàmí, fufu lora oh, o san'wó miliki kuunu ló gbà oh Kórà Benz, katapupu lora oh Af'ọwọ fa lekute, to jẹun tàn toni k'ologbo wà wo òun Àwọn ẹni lọ, lobọ nìkan lo le sọ nípa ọlọdẹ Abuja Tofa coro' lẹ yìn bọn s'ọmọ aja B'ìṣù ẹnì bàtá, f'ọwọ bojẹ T'oba ta yama-yama, d'aṣọ bojẹ Ṣùgbọ'n, ẹní a wí fún, Ọba, jẹ ò gbọ Airpod iPhone ní òní jẹ ò gbọ Ẹbí wọn, kilode? Torí mo ji lapi, 'bọn na wọn ní mo ja wọn ní wire ni Ìbàdàn, ah-ah A ba'tan, a ba'rọba pé òyìnbó tí kowa lẹ́rù nígbàkàn (yeah) Ẹ pé ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá) Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier) Ẹ lọ pé EFCC, toba débi, à jọ má ṣáyé pọ (yayy) (à jọ má ṣáyé pọ) Ayé toto (ayé toto) Ayé akamara (ayé akamara) iPhone lo ko'wó le, ọmọ ase, fufu lora (hello ẹ) Ahn-ahn, kúròńbẹ Ò mọ commissioner (ò mọ commissioner) Ye, òtún mọ Buhari (ha, ò mọ Buhari) Ah, otí rí ọmọ gọ Ọmọ àse ti'odẹ tún mú garri rí (ti'odẹ tún mú garri rí) (kúròńbẹ) Ghetto mo gbè dàgbà, ẹ le p'àjà fún mí lọbọ, Broda Laja (ah, Broda Laja) Ọrọ mí tí d'aleba, kole já tẹbá fa, double seat yin leja (kúròńbẹ) (ahh, okolo) Èmi para-para, wọn lé wojù mí, wọn tún le bami ta'ka (wọn tún le bami ta'ka) Ẹ fẹ pàwọn, taló lọ ń fix Eyimba pẹ'lú Barca? (Pẹ'lú Barca) Kúròńbẹ, mo wọlé, game dẹ change Mora motor lọwọ IVD, mi ò tún gbà change (ẹ gbàgbé ẹ) Abínibí yàtọ' sí ability (yeah) Wọn ja'jakadi, kò dẹ gbàgìdi (o pọ) Ẹ pé ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá) Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier) Ẹ lọ pé EFCC, tó bá dé'bi, à jọ má ṣáyé pọ (à jọ má ṣáyé pọ) Ayé toto (ayé toto) Ayé akamara (ah, ayé akamara) iPhone lo ko'wo le Ọmọ ase, fufu lo ra (ahn, ahn, yea) Kọnga ṣálanga ma ńji jùra lọ Àrà l'ama tí mọ, t'aba jẹun j'ara lọ Àwọn sọlo Makinde, ṣọbọlọyọke Àwọn wèrè, wọn fẹ mọ ìbí t'ati bádé Lapa-lapa mú wọn l'ọpọlọ Ó yá wọn lẹ'nu bí moṣe ńjẹ lọ I'm making money with my tonation Awọn ní àwọn fẹ ṣé investigation I say, "The rhythm moment song tó fantastic Ata di ẹ mo fí sí, t'owa fantasy" Dem say I too dey speak Yorùbá I'm sorry, I no be Calabar Wọn ni mo ji lapi, 'bọn na mo fí mo ja wọn ní wire ni Ìbàdàn (yeah) A ba'tan, a ba'roba pe òyìnbó tí kowa lẹ́rù nígbàkàn Ẹ pé ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá) Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier) Ẹ lọ pé EFCC, tó bá dé'bi, à jọ má ṣáyé pọ Ayé toto (ayé toto) Ayé akamara (ah, ayé akamara) iPhone lo ko'wole, ọmọ ase, fufu lora (ahn, ahn) (fufu lora) (yeah) (kúròńbẹ) Yeah Yeah, who's there? Yeah Yeah Yeah Yeah Yeah Yeah
Writer(s): Temidayo Rapheal Omoniyi, Fakoya Oluwadamilare Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out