Lyrics

Eyi nikan L'adura mi Si Olu Aseda mi Eyi nikan L'adura mi Mo ti mo ona iye yi na Mi o ni ye'se Mi o ni pada Emi o ni si lo Kododo aye ma fe mo oju mi Ju ibi t'ayo mi wa lo Amin Amin Amin O amin oo Eyi nikan le mi nbere Nigba ti mo n mi Ko na t'oluwa mu mi rin yi o K'emi ma se amoju sonu Kin le d'ebute ogo ayanmo K'ogo baba ko tan de opin Imole ko tan de opin aye Fun oruko re nikan (O amin o) O amin O amin O amin O amin o Eyi l'ohun temi n bere Anu ati abo re Owo re at'otito re Ko tan mi l'aye d'ogbo Ani ko se Asa at'Apata Ko ma yo wo ni pe ja mi Eni sare ibi le mi Ko f'ori ara re gbe Gbe'be mi s'ase O amin o (Amin o) O amin O amin O amin O amin o (Amin) Eyi l'ohun temi n bere Awon omo to fun mi Ki won sin o Iwo nikan Ki won ko se rere laye K'alaafia ati ife re Ma joba ni ile wa Opopona majemu ayeraye Ni ka wa o fo titi Alaafia ogbo tutu Ni ipin tawa lodo aseda (Beeni ko ri oo) O amin O amin O amin O amin o Eyi nikan l'adura mi Owo oluwa ko kun mi pupo Ki ina mi jo fun isoji si Labe asiapada bo re Ka sa ko pada l'ohun kan K'ero ijoba re ko po si To ba si de oko iyawo Awa yo ba o joba Adura mi ni Ko se oo (O se O se) O amin O amin O amin O amin o Adura mi ma ti gba Baba mi a gbo Ohun ti emi bere Baba ti se oo Ogede ki n gb'odo ko ya gan (beeni) Baba mi a gbo Elegbede f'owo lu'gi o dun jaye oo Baba ti se oo Omo o le bere akara ka fun lo kuta oo Baba mi a gbo Igbagbo ninu Jesu kin doju tini Baba ti se o Ohun gangan ti mo n bere Baba mi a gbo Ati iran de ran mi Olorun la o ma sin titi Baba ti se o Ke mi o mo fo ojo aye mi si Oluwa Baba mi a gbo Oore ofe ati iferan Olugbala mi si Baba ti se o Kin ma joko l'ese re nigba gbogbo ko eko oo Baba mi a gbo K'emi se yi di ojo ogbo tutu ni mo bere oo Baba ti se o Iran peregun won ki rin wowo kin ku dale (beeni) Baba mi a gbo Ka le wa san mi ju owuro lo Olu nla mo be o Baba ti se o (eeeh amin oo) O amin O amin O amin O amin o Ase Amin Ase o Ema s'amin ase Amin Amin Ase
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out