Lyrics

Óun gbọgbọ lọwọ orí Ayìnde Wasiu mí ọmọ Anifowose Ẹni orí bá bá ṣé ooo Lọn t'aja lọn j'ere lọn lòwò lówó lọn m'owó wálé Wasiu Ọmọ Anifowose ori Àwa dúpé fún Ọlórun ọba ó Berlin lawa yi ọmọ Anifowose ni Germany Koyode mí Thompson, Femí ọmọ Shotire o Andawa Sukura, mọ dùpé lòwò Ọlórun ọba E ṣeun ṣeun mí Awọ tí Alex Bodurin, awọ Adeola Alhaji mí Gbọgbọ yìn eṣe mo dùpé Ké bá mí tọju Abiodun ọmọ Gbajabiamíla mí Àti Waheedi Bodi mí Pẹlu Taiyelolu ọmọ Giwa Giwa awọ Ayìnde mí Wasiu Ọkó Rashida Ololeya sweetie baby Awọ Niyi om'Ojodu, ọkò Lady ko Mariam maya babam Bàbá Suwe óun o mope, Ola bàbá Ṣukura Tọju Kunle Kunle, awọ Saheed ọmọ Rufai Pẹlu Waliu mí gbọgbọ yìn e ṣeun E tọju Abosede baby ọmọ Ayoka mí Saliu Ọmọ ti lo gọmọ lofin ni Ikorodu óò Pessy Ademokun óò, tó bá ń gbó ní Nigeria awọ lọn pẹ orí awọ Àní bí mọba kọrin tí tí tí Un ò je gbàgbé awọ mí l'America Awala san bano Wale ọmọ Balogun o Ọkò Bolanle baby o, Lady Morayo mí bàbá Oyìnda o Alao ọmọ Akindele Ọkò Layide mí larufaya bàbá tonton Demola ọmọ t'Oyefeso alaṣe ni Genesis Bàbá Ololade ọmọ tún tún ó Congratulations mí ó ṣeun bàbá Demola Sikiru Fashek ó, ọmọ Fashola Bàbá ejire ọmọ meji, ọkò Yetunde baby Kó bá mí tọju Lola Lola, l'Ògbómòshó Ìyẹn lolamo Ajala o Mrs Adeniyi Badmus mí Tó bá n gbó'hùn mí ní Chicago awọ lọn pé orí awọ Awọ Enifeni Sikiru, ìyẹn ègbọn dodo ọmọ Omega Sikiru ọmọ Enifeni, ọkọ' Ademífunbi Sekina o Ayo ọmọ Sogunyi bó bá ń gbó ni Los Angeles Ọkò Bolanle baby, má má rórẹ awọ lọ n pé orí awọ Mélé gbà gbé ẹ láì láì Ti n bá kọjá Darkin Raimo Adeola Ọmọ Akujore mí, mother Ayomade Sulaimon Anifowose Yomade óò Debo ọmọ Lamídi mí, At'Okanlawọn, ké bamí tọju chairman Sakiru ọmọ Ajibola, ọkò Mojisola Ololeya, gbọgbọ won ni akinu Germany Adio mí Monsuru, ọmọdun tó ń mí o ṣeun pẹlu láti Odunuga Awọn àbúrò Yomi Yomi, oremí Olowu eye, ìyẹn ọmọ shogunbinikod Awọ Mark Oyetunde, awọ China Owomape, awọ Kenny o kare China o Tí n bá tún dé Belgium Má rántí Dele Dele Ogunkogbiti kogbiti ọmọ Ogunjimi, oyìnbo tó ń tá motor mí Awọ Laye ọmọ Ayeni bi ọjó, ìyẹn Ìjèṣà ọmọ Eleni Atek ọmọ Eleni yemele Mélé gbàgbé Mayor Azeez mí, Mayor n'ilu Belgium mí Awọ Remi Alowonle, ọkó ka Ruka òkè Ibadan n'ile Oluyole ó Imole Moshood ọmọ Onala mí, àbúrò ọmọ Bolaji Nala tó dì olóògbé, Ọlórun bamí sara ba Onala ọmọ Bolaji Ti n bá kọjá ní Amsterdam Mélé gbàgbé é Tunji Tunji ọmọ Olaniran o, Kashokiofula ọmọ Olanihun Àbúrò Gboye mí, Gbenga ọmọ Olanihun Àbúrò Ọmọkayode ọmọ t'Olanihun, orí olówó ní London Awọ Ayìnde, ti sawọ Olamípupo yẹ ó Waka ọkò Ọlóruntoyìn mí, awọ tèmí Ayìnde Awọ Murphy, ọmọ Mojuolape ọkò Sakiratu mí ọmọ Sanusi Òkè Ibadan n'ile Oluyole o, Sakira baby ó Awọ ti Sukanmími ọmọ t'Opadipe ó Taiyelolu ọmọ Somide, Amsterdam É bá mí tọju àbúrò mí Kolapo, àbúrò Yinka Chief Mrs Akindele, ìyẹn áyá Dele Akinyele Oto Akogun n'ilu Ikare, awọ Ayìnde óò O ṣ'awọ Bobo e Femi Femi, é ṣeun Sunday Jeje, gbọgbọ won n'ilu Amsterdam, ẹ má ṣe ọjọ Má tárá ṣaṣa má sáré ló sí Espanyol Màló rí Juliet baby, ọmọ Tenibokun Ibini arogun tayo mí Ní Bendel ṣá nílé wón l'Edo ó Awọ Faith Yinka baby E bá ń tọju Bukky mí, Bukky ni Madrid mí Aburo Chief Femi Femi hero, Borokini of Lagos mí Ọkò Oluwafunmí Aduke, Histon, Texas, magbó bí mó ṣé ń wí Bukky, ẹ má kú itọju mí óò, ní Madrid Juliet Tenibokun Ọlórun a dùró tí ẹ ó, ẹ má kú itọju ọba Oluaye òní Fuji, Ayinde Ade Gbọgbọ ero tọba re London, e bamí ki Yinka Agbekeade Alfa Omega lọn kí ẹ bi etí é bá ń já Awọ Barrister lawyer mí o Titi baby, Titi Adeyemo Ajadi Monsuri mí ọmọ Olumegbon Adio Debayo mí ọmọ Kosoko King Tunde Tunde mí Yinusa, bàbá Egunjobi, ema ku ìtójú ọba Alade koma mí bi eti bá ń já marolẹ Aburo mí Ayìnde mí Wasiu Toju Deji mí connection tó ṣe iyawọ lojo si, ọmọ Olaribigbe Omega lọn kí ẹ omega lọn kí ẹ óò Èwo Wasiu mí Anifowose Omega lọn kí ẹ ó omega lọn kí ẹ Alfa omega o, omega lọn kí ẹ Ọmọlabake Kaotharah, Ademíde b'eti ẹ bá ń já n'ile Marorẹ o, ọkó lọn perí áyá o, mío pé kò kú, mío pe orun o Ko bamí to ọmọmi atolàá, k'iwo gàn gàn kó gùn l'èmí Abimo lè mọ ní tí egbeda, Labake Kaotharah mí Àya Anifowose má gbó bi mọ ṣen wí Omega lọn kí ẹ, omega lọn kí ẹ Alfa omega o, omega lọn kí ẹ Berlin lawa yí óò, ọmọ tó gbolahan mí, ọmọ Anifowose o ri Torí sún sún l'áyé gbà, sún sún ṣa l'àyé Sún sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣa l'àyé Sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣá l'aye Fuji dí sún sún Ayinde Wasiu Sún sún ṣá l'àyé Èyí ní new Fuji music ọmọ Anifowose ó rí Sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣá l'àyé Fuji tún tí sún s'iwaju Ayìnde Wasiu Sún sún ṣá l'àyé Alex Claire Sún sún l'àyé ó gbá, sún sún ṣá l'àyé Alex Claire Sún sún l'àyé gbá, sún sún sa l'àyé Sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣá l'àye
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out