Lyrics

Mo lo soko Mo boluoko Oni nwa gba Isu Oro isu ko londun mi Mo lo sodo Mo boluweri Oni nwa gba-eja Oro eja ko londun mi Mo de inugbo Mo boluode soro Oni nwa gbetu Oro etu ko londun mi Mo de buka Awon ore mi nbuta Won ni nwa pokele Oro ebi ko lonse me Mo ni ya bete Igba nla nii ti mi Won ni nwa mu oguro Oro emu ko lonse mi Mo wa dele Mo ba Ronke mi soro o Oni nwa wora Oro ara ko lonse mi Olufe ni baga Kilo de todorikodo Ni mba ko Ni mba ro Oro gbogbo aiye londun mi Bo ba o pa o Lomo araye o Bi oba o bu lese Lomo araye o Bo ba ni lowo Ka ba eje o Lomo araye o Bo si ni mo Ka ba ese soro Lomo araye o Bo ni iwa to da Ka ba e je o Lomo araye o Bi iwa re osi da Ka yera fun e o Lomo araye o Bo ni ise to da Ka gba mo e lowo Lomo araye o Bi o si rise Ka fi e se yeye o Lomo araye o Bo niyawo to da Ka ba e fe Lomo araye o Biyawo e o si da Ka yimu si e o Lomo araye o Ah! Eniyan bi Aparo Lomo araye nfe ooo ah Eniyan bi Aparo lomo araye nfe Eniyan bi Aparo Lomo araye nfe ooo ah Eniyan bi Aparo lomo araye nfe *Instrumentals* Bo ba o pa o Lomo araye o Bi oba o bu lese Lomo araye o Bo ba ni lowo Ka ba eje o Lomo araye o Bo si ni mo Ka ba ese soro Lomo araye o Bo ni iwa to da Ka ba e je o Lomo araye o Bi iwa re osi da Ka yera fun e o Lomo araye o Bo ni ise to da Ka gba mo e lowo Lomo araye o Bi o si rise Ka fi e se yeye o Lomo araye o Bo niyawo to da Ka ba e fe Lomo araye o Biyawo e o si da Ka yimu si e o Lomo araye o Ah! Eniyan bi Aparo Lomo araye nfe ooo ah Eniyan bi Aparo lomo araye nfe Eniyan bi Aparo Lomo araye nfe ooo ah Eniyan bi Aparo lomo araye nfe
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out