Lyrics

Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un wa dúpẹ o Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá) Al'orin d'owó,orin dolà lo jẹ un wa dúpẹ o Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá) Bi isẹ ba ti l'alubarika opẹ lo yẹ ki eru o da o Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá) Àní bi isẹ ba ti l'alubarika ijó ló yẹ kẹrú ojó Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá) Olú ayé fuji mo gbe eré ta wi de o Ọlọhun lo s'ọlà fuji bo ti rí ọ Ayinde Wasiu ẹrú ń dúpẹ' Bo ba wa dúpẹ ore agbà mi si ó Amuda wa sukura mo dúpẹ-dúpẹ o Gbogbo àwọn to tin lu fuji lati ijọ rí La t'ayé aji saari,aye aji wéré Ko to wa dori fuji ti isẹyin o Bi isẹ ba ti l'alubarika ijo ló yẹ k'ẹrú ojó Orin d'owó orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá Ìbà Sikiru mi ọmọ Abiba l'ọdọfin area Ìbà Ajadi Ganiyu l'oluwọlé Àwọn to kọ lu fuji lati aji wéré Ayinde Muniru ọmọ Mayegun Kao Aminu,Saka Laigbade mo la ó pe o Mufu fuji la wà atí Ayinde the law,l'akarawu area Ajadi lawa l'ewé iná o Jibowu Barrister,Kasali Alani mi yọmi Abinuwaye Basiru,Late Dauda mi Akanmu epo Epo àkàrà n'ibadan ọ'run ẹ re Akande Monsuru Kótó wa dorí Agbaje lọla mi Barry Wonder mi o Doctor Sikiru mi Ayinde Ade o Barusati mí Ìbà ẹ ni mo se ó Agbaje l'ọlá dèdẹgò ori ẹ sa l'ere tiyi padà Ayinla Kollinton baba latika Kebe Kwara mi ibà ni mo se ó Adio Fatai,Ogidan Ololaaju Ayinde Rahimi Bokotẹ Akani Ramoni mi Abiodun Hajji Lao Azeez l'agege ó Iyanda Sawaba mí ewé nla ó Akangbe Waheed ati Famusi mi Alamu aye ó Ati Kabaka ní Ilorin afonja ó Ati Sakariyau mí Danfo ó Emi ọba fuji lo ma ń kí yín ó K1 De Ultimate,akanda elédùmarè t'ayé nfẹ ó Ẹ'yin to ń bọ' lẹ'yìn kẹ kí ará iwaju Ará iwaju oni re lẹ o A ó se fuji yi là fi l'owo lọ'wọ A ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ' (a ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ) A ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ A ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ (a ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ) Walahi talahi Ayinde ó,mo f'ọlọhun búra ọrọ ni Walahi talahi Ayinde ó,mo tún f'ọlọhun búra ọrọ ni Ẹni má báwa du ọrọ yí o,a de Mecca awa le Ọrọ yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o a ní tira tó dájú Walahi talahi Ayinde ó Ẹni ma báwa dù ọ'rọ' yí o,a ní tira tó gboju Ọrọ yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o A de Mecca awá lé (Yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin) (Wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e, wadu e,wadu e) Motun f'ọlọhun búra Ayinde ó,Anọbi Muhamma (Bàbá fa,bàbá fà,bàbá fa,bàbá fà,bàbá fa,bàbá fà, bàbá fa,bàbá fà,bàbá Fatimo) Eyi tí mo wi yẹn (Ọrọ ní,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni) (yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin,yasin) Million,million ní fi ó ojo ojúmọ' ké Ọrọ yí ọ,ẹni ma bámi dù ọrọ yí o A ni sense to m'ori pe Òrò yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o A de Mecca awá lé Ẹ tún ban wípé bẹẹ noni (bẹẹ noni) Ani ẹ ban wípé bẹẹ noni o (bẹẹ noni) Ọlọhun Ọba ló ṣe àdéhùn yio (bẹẹ noni) Baba God ló ṣe àdéhùn yí o (bẹẹ noni) Pe òhun oni fí wa sílẹ fún ìyà jẹ o (bẹẹ noni) Ọlọhun Ọba mu ìlérí ẹ ṣẹ (bẹẹ noni) O ma se mu ìlérí ẹ ṣẹ ó (bẹẹ noni) Gbogbo oni fuji kẹ majo (bẹẹ noni) Kòní re ajo rẹyìn lọla Ọlọhun mi àmìn (bẹẹ noni) Ẹyin lon di àkùkọ ọmọ Gbolahan àbí (bẹẹ noni) Ẹyin lon di àkùkọ ọmọ Gbolahan Ayinde (bẹẹ noni) Ẹ wí pé bẹẹ noni o (bẹẹ noni)
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out