Lyrics

Heee Mo f'ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re Owo nla to gbe gbogbo aye duro Mo f'ogo o f'oruko re Ògo-ogo-ooo Mo f'ogo f'oruko re (Ògo o) Mo f'ogo f'oruko re (Ayeraye ó) Owo nla to gbe gbogbo aye duro (O se eeee) Mo f'ogo oo F'oruko re. (Ogo, ogo ninu ogo) Mo f'ogo f'oruko re (Ayeraye ó) Mo f'ogo f'oruko re (Ijinle ni ọ o) Owo nla to gbe gbogbo aye duro Mo f'ogo oo F'oruko re Sometimes I wonder who you really are And am amazed lord at your glory People call you yahweh eh Some call you alpha Onise iyanu, ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re (ayeraye) Owo nla to gbe gbogbo aye duro Mo f'ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re Owo nla to gbe gbogbo aye duro Mo f'ogo f'oruko re Orun s'oro ogo re Ofurufu won f'ise re han ijinle ni o Asiri orun ohun aye Ogbe gbogbo aye si ikawo Gbogbo aye dabi elega Awon agbagbagba merinlelogun n so ti imole re Ajinde ati iye, ogo foruko re Mo f'ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re Owo nla to gbe gbogbo aye duro Mo f'ogo f'oruko re Ogo, ogo, ogo si o Mo f'ogo f'oruko re Mo f'ogo f'oruko re Owo nla to gbe gbogbo aye duro Mo f'ogo f'oruko re (Ijinle ni o Olorun) Mo f'ogo f'oruko re (Monamona se oju orun moromoro) Mo f'ogo f'oruko re (Onile ola mo gbe o ga o) Mo f'ogo f'oruko re (Aditu, Adimu, Adiwo) Mo f'ogo f'oruko re (Mo wa rin labe itise re) Mo f'ogo f'oruko re (You are a problem solver) Mo f'ogo f'oruko re (Ase lenu awon omo oni) Mo f'ogo f'oruko re (A o wa, a la o ri rara baba o) Mo f'ogo f'oruko re (A o pe, a ni o daun o) Mo f'ogo f'oruko re (Ina inu apa ti o se pa baba) Mo f'ogo f'oruko re (Mo f'ogo f'oruko re o) Mo f'ogo f'oruko re
Writer(s): Yomi Olubunmi Adeoye Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out