Listen to EverGreen Yoruba Medley by Laolu Gbenjo

EverGreen Yoruba Medley

Laolu Gbenjo

Christian & Gospel

2,110 Shazams

Lyrics

Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán o Ọba mímọ l'ọ'ba t'emi n sin Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán o Alágbára mo mọ 'rukọ rẹ Lẹ'yìn Jésù kò má sẹ' ni kán o Ọba mímọ l'ọ'ba t'emi n sìn nígbà gbogbo lojojumọ' Lẹ'yìn Jésù ko má sẹ' ni kán o Alágbára mo mọ 'rukọ rẹ Lẹ'yìn Jésù ni mímọ Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán ó (Ọba mímọ má ni) Ọba mímọ l'ọ'ba tí mo n sìn (Lẹ'yìn Jésù) Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán ó (Alágbára gíga ní o) Alágbára mo mọ 'rukọ rẹ Jésù olùtọ́jú ènìyàn Alágbára gíga-gíga gíga-gíga Lọrun àti láyé bàbà mi mímọ o Òdì kan gbé rẹ ni ja Ọlọ'wọ'gbọgbọrọ tí ń yọ mọ rẹ lofin ayé Àárín má tọ'ka lẹ'yìn Ogberin lẹ'yìn aṣo' dodo bàbá Mímọ' Sárà rẹ náà re Baba olùtọ́jú ènìyàn Sárà rẹ náà re Olùtọ́jú mi nígbà gbogbo ẹ ṣé o Jésù olùtọ́jú ènìyàn (Sárà rẹ ó ooo) Sárà rẹ náà rẹ (Atobajaiye Elédùmarè bàbà mimọ) Baba olùtọ́jú ènìyàn (Eh Sárà rẹ) Sárà rẹ náà re Èmi o màmà rí ọ rí o Ọlọ'run mi Ṣùgbọ'n mo rí 'ṣẹ rẹ nínú ayé mi Èmi o màmà rí ọ rí o Ẹlẹ́dàá mi Ṣùgbọ'n mo rí àánú rẹ nínú ayé mi bàbà o Eh! I have assurance Ọlọ́run mi bàbà mímọ Wípé ẹ wa I have assurance Ọlọ́run mi wípé ẹ wa Èmi o rí ọ rí o Ọlọ'run mi Ṣùgbọ'n mo rí 'ṣẹ rẹ (Ṣùgbọ́n mo rí àánú rẹ nínú ayé mi mo rí' ọwọ rẹ bàbà mímọ) Èmi o rí ọ rí o Ọlọ'run mi Ṣùgbọ'n mo rí 'ṣẹ rẹ La la la la la la la la Olúwa o I have assurance Ọlọ́run mi Wípé ẹ wa I have assurance Ọlọ́run mi wípé ẹ wa Ọlọ'run mi Ọlọ'run mi Ìwọ lójú tí mo fí ń ríran Ìwọ ni kọ'kọ'rọ' tí mo fi ń ṣílẹ̀kùn Ìwọ l 'orin tí mo ń kọ eh Ina ayé ẹ ò jẹ' kó jo mi Kí ni mo ní ti mo lè fún ọ o Mo wólẹ' mo ki ọ ó bàbà Ọlọ'run mi Ìgbà tí mo rò ó Ìṣe' yanu rẹ lórí mi Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Bàbá Àní Ìgbà tí mo rò ó Ìṣe' yanu rẹ lórí mi Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga pupọ Ìgbà tí mo rò ó Ìṣe' yanu rẹ láyé mi Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Bàbá Ìgbà tí mo rò ó Ìṣe' yanu rẹ láyé mi Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Mo rí pé ó ga Bàbá Bàbá ń f'aye mi dá bí rà ooo Bàbá ń f'aye mi dá bí rà (O f'aye mi dà bí rà dá bí rà) (O f'aye mi dà bí rà dá bí rà) (Ṣáá má wo mí ẹ rọra wo mi) (Ṣáá má wo mí ẹ rọra wo mi) Edumare f'ayé mi dá bí rà sẹ o Bàbá ń f'aye mi dá bí rà o Lójú ọ'tá mi o gbé mi lékè Bàbá ń f'aye mi dá bí rà Lójú ẹlẹ'tan ó wá s'ẹkún mi d'ẹ'rín ṣẹ oo Bàbá ń f'aye mi dá bí rà Ó ra mi padà ó wà sọ mé d 'ọmọ rẹ Eledumare Ẹ ṣé o Bàbá ń f'aye mi dá bí rà Lójú ọ'tá mi o gbé mi lékè Bàbá ń f'aye mi dá bí rà
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out