Lyrics

Halleluyah o, aṣọ'pẹ (Ah) Kasi ma yọ Halleluyah, aṣọ'pẹ Kasi ma yọ Ọdun to wo'le o To ṣoju ẹmi wa Ko ba wa layọ Ati ṣẹgun ọta o Toni koni ṣoju wa Oju wa tẹlẹ gan Ni'woyi amọdun o Owo nini pẹlu ọmọ rere Ile kikọ pẹlu ẹmi gigun Alafia lo joun gbogbo lọ Edumare ma fi kan han wa Halleluyah, aṣọ'pẹ Kasi ma yọ Halleluyah, aṣọ'pẹ Kasi ma yọ (Yes) Ọdún to wole o To ṣoju ẹmi wa Ko ba wa layọ Ati ṣẹgun ọta o Toni koni ṣoju wa Oju wa tẹlẹ gan Ni'woyi amọdun o Owo nini pẹlu ọmọ rere Ile kikọ pẹlu ẹmi gigun Alafia lo joun gbogbo lọ Edumare ma fi kan han wa Ọpẹ yẹ Eledumare ọba o Ọpẹ lo yẹ ọ, baba mimọ Adupẹ lọwọ rẹ o, onibu ọrẹ Tori ọta lun'lu ibajẹ, ọba Oluwa ko ma ni jẹ ko dun B'oba lọ ṣẹṣẹ dun, ọmọ ọta nì o ma jẹ o r'ọdun tuntun Tori Ọta n lémi Wan o le bami Wan sare titi d'ọdọ Jesu Moní Jésù olore ọfẹ Mo boju w'ẹyin, awọn ọta ṣubu Wan ṣubu lulẹ, wan sun fanfan Mo bere wo, kilo gbe wan ṣubu? Wan ni, Ọrọ Oluwa lo sowipe Nipa eso wan la o fi mọ wan Ah, nipa iwa wan la o da wan lẹjọ Ọta n lémi Wan o le bami Wan sare titi d'ọdọ Jesu Moní Jésù olore ọfẹ Mo boju w'ẹyin, awọn ọta ṣubu (Yes) Wan ṣubu lulẹ, wan sun fanfan Mo bere wo, kilo gbe wan ṣubu? Wan ni, Ọrọ Oluwa lo sowipe Nipa eso wan la o fi mọ wan Nipa iwa wan la o da wan lẹjọ
Writer(s): Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out