Listen to Gbeja (feat. Alh. Wasiu Alabi Pasuma) by Qdot

Gbeja (feat. Alh. Wasiu Alabi Pasuma)

Qdot

World

76,650 Shazams

Lyrics

Pasuma wonder oh Ìjọba Fuji oh Bàbá Wasila Daddy Rokiba Qdot lórúkọ mí (2T upon deebeatz) Kòye wọn Wọn fẹ mọ'di abájọ mí Wọn fẹ mọ'lé bàbá alájọ mí Ọtá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh Bàbá mí lókè ńpá mí mọ Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Oṣó ń gb'ogun, ọ'tá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà) Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà) Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà) Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà) Ẹ jẹ kà dúpẹ' pé ènìyàn kò ló l'Ọlọrun wá Kà lènìyàn ní, ènìyàn lé ní k'òjò má ro, sùgbọn Àdúrà lógbà, àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọn Kín má wọ jersey, kín má wọ bootu Penalty mí ó lé jẹ'rín Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà) Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà) Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà) Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà) Èmi lẹni t'ayé tí ro (t'ayé tí ròpìn oh) Pé kólé dá ń kán 're ṣé o ('re ṣé o) Ṣùgbọn, mó rí àánú ẹ gbà, Olú Ọ̀run o, lo bamiṣé oh (Alabi oh) Wọn sáré, sáré, sáré Olúwa júwọn lọ Wọn gb'ero pé kó bàjẹ́ ní, orí mí ó gbàbọdé o (Paso) Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Àdúrà lo ń gbà àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà) Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà) Ìṣẹdà mí gbéjà mí jà (gbéjà) Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà) Bàbá mí tí ṣé, Bàbá mí tí ṣé, Bàbá tí ṣé Oùn t'aye rope kò ṣé-ṣé, Abaniṣe tí bámí ṣé Òun tímo wá lọ Sokoto, o ń bẹ l'apo ṣòkòtò mí Ọmọ tóní kólé pa'gan, ó ko'lé alarinrin Àdúrà lógbà (àdúrà lógbà) Àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọn Kín má wọ jersey, kín má wọ bootu Penalty mí ó lé jẹ'rín Wọn fẹ mọ'di abájọ mí (mọ'di abájọ mí) Wọn fẹ mọ'lé bàbá alájọ mí (bàbá alájọ mí) Ọtá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh Bàbá mí lókè ńpá mí mọ Wọn rò pé ó tàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Àdúrà lo ń gbà àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ) (2T on the mix)
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out