Lyrics

Pipele,Pipele lo n pele o Pipele,Pipele lo n pele o Pipele,Pipele lo n pele ooo Pipele,Pipele lo n pele o Kaka k'ewe agbon de Pipele lo n pele Kaka k'oro iya aje, O fi gbogbo omo re b'obirin Kaka k'ewe agbon de Pipele, Pipele lo n pele o Pipele,Pipele lo n pele o Pipele,Pipele lo n pele o Pipele,Pipele lo n pele ooo Pipele,Pipele lo n pele o Kaka k'ewe agbon de Pipele lo n pele Kaka k'oro iya aje, O fi gbogbo omo re b'obirin Kaka k'ewe agbon de Pipele, Pipele lo n pele o Ye, Oluorun o Dide wa ran wa l'owo o Gbo ohun ebe wa, ni Naijiria yi o Olododo o si mo, won s'aye di je ki n je Igunnugun yan ni je, Akala yan ni je, o lo o Ye, Oluorun, Eledumare, wa ko wa yo A n be o, Oluwa, dide ko gba Isakoso Yi igba buburu pada si rere fun wa Ounje to won, so won d'opo fun wa Mekunnu n jiya, Eledumare wa ko wa yo Rogbodiyan ile aye yi papoju, la se ke si o o Lai si ese, ijiya o si o, Eledumare wa darijini Pipele,Pipele lo n pele o e Pipele,Pipele lo n pele o Pipele,Pipele lo n pele si i, lojojumo o Pipele,Pipele lo n pele o Kaka k'ewe agbon de Pipele lo n pele Kaka k'oro iya aje, o fi gbogbo omo re b'obirin Kaka k'ewe agbon de Pipele, Pipele lo n pele o L'aye ojosi, b'omo ba ka iwe mefa Bi eni ka gbogbo iwe ni o o Iwe kika jo'ju, laye ojosi, b'omo ba ka iwe mefa Bi eni ka gbogbo iwe ni e e Sugbon l'ode oni o, aye ti d'obiripo Omo re Yunifasiti, o ri bi eni re je'le-osinmi Omo ka gbogbo iwe tan O wa se, wa se o, ko ma ri 'se fi se Ki l'anfaani Satifike t'a gba ta o ri 'se fi se Ki l'afaani ile iwe t'a lo, t'a jade ti a o ri'se Ebe la be yin, eyin ijoba E ba wa, w'ono abayo, tori Owo to ba di'le, l'esu n ran ni'se, eyi l'adigunjale fi po o Iwa ibaje lorisirisi, ojoojumo lo n gbile si Ka maa pa'ra wa, bi eni p'eran Ko ti le, jo wa l'ojumo 419 lorisirisi, iwa ibaje d'oun a mu s'oge Awa n be o Eledua, Baba, ma se wo wa ni'ran Tete je ki'joba re de, k'a se bere lori ase'bi Ki'na Orun sokale wa o, ko jo gbogbo imo esu run Ki iya to n je Olododo, ko le d'oun igbagbe o Ko le d'oun igbagbe o Ko le d'oun ari'pitan Ko le d'oun igbagbe o Ko le d'oun amu'pitan Si'ju aanu re wo wa o Edumare wa tun Naijiria yi se Si'ju aanu re wo wa se Edumare wa tun Naijiria yi se Orileede yi n fe atunse Edumare wa tun Naijiria yi se A ti f'otito pamo, iro nikan la n pon o Edumare wa tun Naijiria yi se A f'oun to ye sile, ase'yi ti ko ye Edumare wa tun Naijiria yi se Ah! Oba Edumare dakun gba wa o Edumare wa tun Naijiria yi se Ninu rogbodiyan ile aye yi Edumare wa tun Naijiria yi se Omo ka iwe tan, e mo ri'se fi se Edumare wa tun Naijiria yi se Eni n s'ise da bi ole o Edumare wa tun Naijiria yi se Igbe ole loni, igbe ole lola Edumare wa tun Naijiria yi se 419 lorisirisi Edumare wa tun Naijiria yi se Bee, ita'jesi'le l'o'lokanojokan Edumare wa tun Naijiria yi se A wa da bi agutan ti ko l'oluso o Edumare wa tun Naijiria yi se Ki iya to n je Olododo, k'o le d'oun igbagbe o Ko le d'oun igbagbe o Ko mo le d'oun ari'pitan Ko le d'oun igbagbe o Ko le d'oun amu'pitan Si'ju aanu re Baba o Edumare wa tun Naijiria yi se Jowo dakun Baba si'ju aanu re wo wa Edumare wa tun Naijiria yi se Gbogbo wa n w'odo b'ose n gbe'gi Arere lo o Edumare wa tun Naijiria yi se Igba ti Odo n gba'rere lo o Edumare wa tun Naijiria yi se Ba wo ni, Ba wo ni, t'Araba yo se ri Edumare wa tun Naijiria yi se Ba wo l'eyin ola awon omo wa yo se ri Edumare wa tun Naijiria yi se Ebi ti so'po eniyan d'alarinkiri Edumare wa tun Naijiria yi se Won n se "Bambi Allah" ki won to jeun Edumare wa tun Naijiria yi se Won n se "Bambi Allah" e bun mi nitori Oloun Oba o Edumare wa tun Naijiria yi se Asita ibon n d'emi awon eyan l'egbodo o Edumare wa tun Naijiria yi se Awon agbesunmomi n fooro emi wa Edumare wa tun Naijiria yi se Let the killings stop! Let the violence cease! Edumare wa tun Naijiria yi se T'oba je t'ese, Baba darijini Edumare wa tun Naijiria yi se F'orjiwa dakun, s'aanu fun wa o Edumare wa tun Naijiria yi se T'oba je t'ese, Baba a be o Edumare wa tun Naijiria yi se Edumare, Edumare, Edumare Edumare o Ki iya to n je Olododo, k'o le d'oun igbagbe o
Writer(s): Bukunmi Babarinsa Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out