Lyrics

Eje ka fope fun o e Iwa Olorun ni iyin to po Eru ipaa re po o e Be laanu re duro o lai-lai Eyin o Oluwa o halleluyah Egbe e ga o halleluyah Eyin Oluwa o halleluyah O hun logaju o halleluyah Yin oun to fogbon da orun Yin oun to lewa ninu ogo Yin oun ti Kerubu Serafu korin si o Oun re ru awon omi okun Eeyin o Oluwa o halleluyah Egbe e ga o halleluya Eyin Oluwa o halleluyah O hun logaju o halleluyah Nitori tori majemu ati pinlese Nitori tori ododo re ti kosaki Nitori irele ati fe re siwa Nitori agbara re topo pupo Eyin o Oluwa o halleluyah Egbe e ga o halleluyah Eyin Oluwa o halleluyah O hun logaju o halleluyah Yin in tinu tinu u re Yin in gbogbo to okan tara a Yin in bawon torun un o o o Oun loni ife e waju lo Eyin o Oluwa o halleluyah Egbe e ga o halleluyah Eyin Oluwa o halleluyah O un logaju o halleluyah Eyin o Oluwa o halleluyah Egbe e ga o halleluyah Eyin Oluwa o halleluyah O un logaju o halleluyah
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out