Listen to Elu Agogo by Florocka

Elu Agogo

Florocka

Christian & Gospel

224 Shazams

Lyrics

Rah rah rah Rah rah rah rah Elu agogo Elu agogo Elu agogo Kèrèsimési Elu agogo Elu agogo Olugbala wa dé o Elu agogo Elu agogo Elu agogo Elu agogo Kèrèsimési o Elu agogo Elu agogo Olugbala wa dé o Elu agogo Awon olusó agutan Won só ago won Imole yi won kà Won ni kilode o Asé Olugbala la bí (Olugbala wa káàbó) Awon olusó agutan Won só ago won Imole yi won kà Won ni kilode o Asé Olugbala la bí (Olugbala wa káàbó) (Ehh yeah yeah, yeah yeah, yeah yeah) (Elu agogo) Elu agogo Elu agogo Elu agogo Kèrèsimési Elu agogo Elu agogo Olugbala wa dé o Elu agogo (E bami lu agogo) Elu agogo (Agogo ayo) Elu agogo Elu agogo (Agogo eda, say yeah) Kèrèsimési o Elu agogo Elu agogo Olugbala wa dé o Elu agogo Irawo kan iyan loju orun Si awon omo yen meta Awon angeli ko orin loke o Pe Olugbala ti de Olugbala wa káàbó (Olugbala wa káàbó) (We welcome you Lord, yeah...) E fi ope fun Baba (Baba) E fi ope fun Omo (Omo) E fi ope fun Emi mimo fun Baba Ara aiye Olugbala wa káàbó (Olugbala wa káàbó) (We welcome you Lord, yeah...) (Elu agogo) Elu agogo (Yeah eh yeah) Elu agogo Elu agogo Kèrèsimési (Go tell it on the mountains) Elu agogo Elu agogo (Over the hills and everywhere) Olugbala wa dé o Elu agogo (E bami lu agogo) Elu agogo (Agogo ayo) Elu agogo Elu agogo Kèrèsimési o (Go and tell it everywhere) Elu agogo(Tell somebody) Elu agogo Olugbala wa dé o Elu agogo (Away) O de O de o Obanla de o, wura de (E wi) O de O de o Obanla de o, wura de O de O de o Oba eri ma de, o ma ti de O de (E je ko wole wa) O de o Obanla de o, wura de O de O de o Obanla de o, wura de O de (E si ilekun o) O de o (E je ko wole wa) Obanla de o, wura de E gbe ori yin soke Eyin e nona anikajumo Gbe yin soke Eyin ekun aiyeraye O de O de o h Obanla de o, wura de He comes See him coming I can see the King of Glory coming O de (The gates of hell) O de o (shall not prevail) Obanla de o, wura de Said I can see The Glory of the Lord Coming upon me O de O de o Obanla de o, wura de Oh oh oh yeah...
Writer(s): Akinwunmi Akiremi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out