Lyrics

Iya ati baba wo n bimida Emi gan gan motu n tù rá bi Loruko wu n sé Dara sí Iya ati baba wo n bimida Emi gan gan motu n tù rá bi Loruko wu n sé Dara sí Gboju wolorun bi karakata ni mo fé Ki ń ti toju mommy toju daddy ni mo fé Wo ni pè mo razz wó n pé mi la si bí omo Wó n mó pé agan mi to tadi mayin bó la tíbi omo Ò dee n jama jama kó n ma pé ko si future I start to hustle hard no any artist to fé feature Worry on my life zino ni pe ki n womisishan Never stopping la fi awo da Makana is on a mission No be lie since 2020 fans no Dey see me Many obstacles but die hard fans still dey feel me Awon to jeju mi lojosi go still see me win Blessing me ma loud yoruku lenu bu chimini Iya ati baba wo n bimida Emi gan gan motu n tù rá bi Loruko wu n sé Dara sí Iya ati baba wo n bimida Emi gan gan motu n tù rá bi Loruko wu n sé Dara sí Wo n ki n sópe ko modé ma dete Tó bá ti lé da igbo gbé Mó n high Lori no realer Eru iku tolé da igbo gbé Omo ologo gbogboro tó n para biti mayweather Shere Nile ma wó nu ojo Shey you see the may weather Cause eru iku lo ma n jé ko mo Sha won pelu jekonmo Aso Gucci sokoto amiri lo n ma je ko wó Oruju ni je ki ó han Ojo esin mi mio ni je ko ró Mo gbélefo to le wole ogba mi o ni decorum If you know the struggle you go know the pain Life wasn't easy my brother if you dey the game Them say money no be fame Them say Bobby no be tail I for don peme if no be GOD and cause say OG dey Iya ati baba wo n bimida Emi gan gan motu n tù rá bi Loruko wu n sé Dara sí Iya ati baba wo n bimida Emi gan gan motu n tù rá bi Loruko wu n sé Dara sí Omo gidi sha lo ye Kaya Kasitun Jari koshe rere ni tori awon ewe ni ojo iwaju Boy she rere o boy o shere oooooo Ba siko bato oluwaye Fuji ma baye tie loo Ere n Su siwaju ko fi igba kan duro ooo Eya to bo oko yi daju daju amule lebute ayo o Emi Loni Fuji mi Tori o Nilu o ni fortune Igbakan loor igbakan boo Gbogbo igbakigba wa eledumare je ko ba wa laramu Isè to sé omo fu ogún odùn Iyà to jomo fosu mefa bi o ba Kpomo A Simi leyin omoni Melo ni ko se o melo ni ko se o Melo no ko se ile ayé oo Melo no ko se le ayé ooo Da da pam da da pam pa pa pam pada Todo ton to to to to Melo no ko se le ayé ooo no one but God Ayinde wasiu mi te ni n teni teni Ba n da kasa fu omo anifowose o Eh a ehhhh huuuuuuu Ba n da kasa fu omo anifowose o Eh a ehhhh huuuuuuu
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out