Credits

PERFORMING ARTISTS
Haruna Ishola [M.O.N. Baba Ngani Agba] and His Apala Group
Haruna Ishola [M.O.N. Baba Ngani Agba] and His Apala Group
Lead Vocals

Lyrics

Ejo mo gbare mi de Eyin sanmori oni faaji o Ejo mo gbare mi de Eyin sanmori oni faaji o B'ina ba wole okunkun n lati salo o Ina ran ta lo ma jo Ina ti ran e feti sibi Ebere e mujo ina ran Ina ran o'komo ti yoo t'owo b'eru Ina ran e sedi wuke E mowo kan sori E mowo kan si bebere idi Ki e mi a jo lo Olomi dakun dakun jowo Sun momi dakun dakun baby mi Ko rotate patapata Ina ti ran e feti sibi Ebere e mujo ina ran Ina ran o'komo ti yoo t'owo b'eru Ina ran e sedi wuke E mowo kan sori E mowo kan si bebere idi Ki e mi a jo lo Olomi dakun dakun jowo Sun momi dakun dakun baby mi Ko rotate patapata Sisi wo mi loju naa (ehnnnnnnn) Sisi wo mi loju naa (ehnnnnnnn) E wo bo se fine Bebedi e n soro Dakun kalo wa mo le mi Osere oju n ko bi amonamona Gbogbo ara n ko bi ajulo Onimu sinsin ju kele Gbogbo boys won patewo Wa Wa Wa wa wa B'obinrin ba dara bi oni wa Bo ba gba kobo kan abo Mi o le fe B'obinrin ba dara bi oni wa Bo ba gba kobo kan abo Mi o le fe B'obinrin ba niwa tutu Bo tun rewa Mo le fi one thousand fe B'obinrin ba niwa tutu Bo tun rewa Mo le fi one thousand fe Jaye jaye e ba wa jo E ba wa yo Awa la n logba lojo aye gbogbo Kigba ma se lowa laye Ka riire gba Jaye jaye e sun bata E fijo be Kosi ya were leko Mo fe ke mo Awon asa ti won tun gbede niyen Soyoyo ti lo Imii tuntun latun fe gbo ooooo
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out