Lyrics

Let us see you dancing Eyyy To ba Gbo pe Idemi ja O ye ko ti mo Pe Sekeseke ti bo To ba Gbo pe Idemi ja O ye ko ti mo Pe Sekeseke ti bo Oluwa L' oluso agutan mi Ohun Oluwa na de ni mo gbo Oro Oluwa Iye ni Oya la eti re ko je ko wole Oro tin o mu Omo toti sonu To mu omo yen pade rele Faith is my Currency Oya ka Bible e ko ko fi cash out (Ko fi cash out) His mercies are new Every Morning Oya subscribe ko to step out (Ko to step out) Nigbati ebi npa mi Jesu ni bread of Life Jesu je oku dide Jesu eternal Life Jesu funmi ni Alafia Lai si ni Nasarawa Isimi Wa ninu jesu Omo ope Oya sarewa Goodness and mercies dey follow From now until tomorrow And everything way I get omo Na my own me I no borrow Ninu aye, Jesu Yomi kuro O ramipada o wa so mi d' omo Mo wa dupe lowo Aye Raye (Aye raye) Ninu aye, Jesu Yomi kuro O ramipada o wa so mi d' omo Mo wa dupe lowo ayeraye (Ofun Mi Ni) Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe His Goodness and Mercies Is Uncountable Anytime wey Call o wa available In the Presence of enemy You Prepare a Table O de je kin wa comfortable Ogo, Ogo Oya gba gbogbo ogo ogo Iwo le ye lati gba gbogbo Ola agbara imo Ati gbo gbo ogo Judah, Judah Lion of the tribe of Judah Awon agbagba merinlelogun Wole niwaju re won wa Juba (Won wa Juba) Judah, Judah Lion of the tribe of Judah Awon agbagba merinlelogun Wole niwaju re won wa Juba Aribi Rabata, (Aribi Rabata) Araba Ribiti, (Araba Ribiti) Ise ti baba nse kabiti kabiti (Kabiti kabiti) Tani, tani, tani, tani Emi ma tele (Jesu) Tani, tani, tani, tani Emi gbekele (Ofun Mi Ni) Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe (Ofun Mi Ni) Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out