Lyrics

Olorun lo le fun ni layo Eniyan ole funi layo kope Bo pe titi oo akololo a pe baba Oba oke lo layo pupo lodo Funmilayo Funmilayo Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi Olorun lo le fun ni layo Eniyan ole funi layo kope Bo pe titi oo akololo a pe baba Oba oke lo layo pupo lodo Funmilayo Funmilayo Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi Bi emi basi wa laye ireti o pin oo Atoro ohun gbogbo lowo olorun ki kan ju o Oro olorun ko ni lo laiye se laye Bi omo kiniun wonma kigbe ebi kikan Awon to gbekele ki yo shale yi ri ohun ti o dara Olorun lo le fun ni layo Eniyan ole funi layo kope Bo pe titi oo akololo a pe baba Oba oke lo layo pupo lodo Funmilayo Funmilayo Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi Bi igba ban gba ni ejiki ama ro ju Igba nbo ti o gba ni olorun lo ni dede Ironu o da nkan Ore lo ni suuru Eti olorun ko wu wo lati gbo igbe wa Igba gbo ninu Jesu lo le mu ni se ase yege Olorun lo le fun ni layo Eniyan ole funi layo kope Bo pe titi oo akololo a pe baba Oba oke lo layo pupo lodo Funmilayo Funmilayo Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi Gbe okan le jesu apata ti kin ye Matori a ro pin ko se si eleda re Pada leyin aiye ni se ni won to ni pa Aiye a funi ni fila a fi gba odindin ori eni l'owo eni Won ti mi a si regun ko ni wu won de ti gbe san Olorun lo le fun ni layo Eniyan ole funi layo kope Bo pe titi oo akololo a pe baba Oba oke lo layo pupo lodo Funmilayo Funmilayo Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi Ori to mi a da de ko ma ni se a i de Funnnnnmilayo Baba fun mi layo ma je ki temi o gbe oo Funnnnnmilayo Ohun to ye mi o baba ma fi dunmi o baba rere amin Funnnnnmilayo Oro ti mo ba araye wi to ya gere ba mi se baba Funnnnnmilayo Mo mope omo to mi a gun eseee re a tirin Funnnnnmilayo Gbogbo a sise jeje eleri e je kalo mu suuru A fe re bo na Funnnnnmilayo T'ori koko to mi a j'ata idi re a koko gbona, uh uh uh Funnnnnmilayo E je ka se fun olorun loke loke l'owo a fun ni gbe eyen je oto Funnnnnmilayo Ohun ti afe gba l'owo olorun oju ohun ti a le fun lo eh eh Funnnnnmilayo Eni ba fe jeun gboingboin ati eleku gboingboin, tooto niyen Funnnnnmilayo
Writer(s): Tope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out