Lyrics

Lo'gun ofe Ahoo! (Lo'gun ofe) Ode o! (Lo'gun ofe) Omo w'omo le a fili ja(L'ogun ofe, l'ogun ofe lo'gun ofe) Qdot l'oruko mi! Irukere Oba lema si lowo mi! T'eba ti ri mi, ke fun mi lowo mi! Mi o b'anybody ja s'oba! T'eba ti ri mi, ke fun mi lowo mi Aare Ona Kakanfo Ebun mi lowo mi Aare Ona Kakanfo Jagunjagun nimi, e ma ri mi fin Aare Ona Kakanfo Akinkanju okunrin loju ogun Aare Ona Kakanfo Yerepe oni'bikan t'a ma gba mu Aare Ona Kakanfo Malo di mu, koma di'na mu Aare Ona Kakanfo Awon omo Oduduwa mi o fi mi s'ere Aare Ona Kakanfo I deserve some accolades Aare Ona Kakanfo Yeah yeah yeah yeah E duro na, ke je n'soro E je n'so t'enu mi Won d'ohun m'agogo lenu T'ori kuku luku s'ewe gelu gelu T'ori af'aja s'ole Aja p'oun l'oba ekun Ara me riri, mo r'emo ki lo fa t'alantakun l'eri s'alabahun If you don't like me, I don't like you Forget the Yoruba I spoke oh Ma p'agbada fun mi ni raincoat oh Mo ti j'elo o, ko s'ohun t'efe se K'asewo to ko petesi oju ri E so f'ologini to f'oju j'ekun Ko mo'ru eranko to ma ba t'ahun ni'gbo Irukere Oba lema si lowo mi! T'eba ti ri mi, ke fun mi lowo mi! Mi o b'anybody ja s'oba! T'eba ti ri mi, ke fun mi lowo mi Aare Ona Kakanfo Ebun mi lowo mi Aare Ona Kakanfo Jagunjagun nimi, e ma ri mi fin Aare Ona Kakanfo Akinkanju okunrin loju ogun Aare Ona Kakanfo Yerepe oni'bikan t'a ma gba mu Aare Ona Kakanfo Malo di mu, koma di'na mu Aare Ona Kakanfo Awon omo Oduduwa mi o fi mi s'ere Aare Ona Kakanfo I deserve some accolades Aare Ona Kakanfo Yeah yeah yeah yeah Ti ko ba nidi, a ki nr'eja loke odo T'owo ba ti gb'owo eyin, enu oni le s'ododo Before before, I dey do like mumu for dem Dem dey do face like a Lion Felefele ni won bi ti nylon Yiyo ekun t'ojo ko Ema f'eko ta'na fun mi je Kanakana ko ma na'mo ega Agbado inu'go f'adiye, awomoju ni T'omi o ba to lati we, afiboju ni Dont feed me what I don't eat The fall of a dry leaf, is a lesson for the fresh one L'ogun ofe ooh L'ogun ofe (k'ara o le baba) Aare Ganiyu Ige Adams The 15th Aare Ona Kakanfo fun gbogbo Ile Yoruba Jagunjagun f'awon Yoruba ooh Aare Ona Kakanfo Ooni of Ife, Alase'gba keji Orisa Aare Ona Kakanfo Ojaja Keji, Arole Oodua Aare Ona Kakanfo Mo m'alaafin Oyo Aare Ona Kakanfo Iku baba Yeye, Iku t'o pa ku je Aare Ona Kakanfo Mo ki'joye, Mo ki gbogbo Oba Alade ooh Aare Ona Kakanfo Gbogbo Omo Yoruba n'ile l'ajo Aare Ona Kakanfo IBD Dende Aare Ona Kakanfo Aremo Oni'ru, Akin Shittu olori Eyo Aare Ona Kakanfo Femi Jaguar, Shina Pellerr Aare Ona Kakanfo Fuad Oloto, Laolu Selfmade Aare Ona Kakanfo Sir Kuti ko f'agidi, Billy Q, El-Dubai (Climax) Olu-omo f'olagbade wa ni Bangla Re Aare Ona Kakanfo Santay Olorun-toyin ni Bombay Aare Ona Kakanfo Taiyeolu fo ni Toronto ooh Qdot l'oruko mi oooh...
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out