Listen to Fura Sára by Brymo

Fura Sára

Brymo

Alternative

2,095 Shazams

Lyrics

O pa mi l'ekun O wa a funmi l'akara jẹ Mo sunkun, mo gbọn'ju Oni n sare lọ s'ọja Bo wunmi n bu'gi jẹ Eh, ah-ah, ah, ah-ah, ah, ah-ah, ah, ah-ah, ah Oloomi dakun, jọọ o, dakun, jọọ o Ye gbọ t'ẹlẹgan Ye gbọ t'ẹlẹgan Ye gbọ t'ẹlẹgan Fura si wọn Gbogbo aja on'ija ja O n ja fun araata Bo ba ya wa lanu gbaga Wa l'emi mo ṣe aida Ah-ah, ah, ah-ah, ah, ah-ah, ah, ah-ah, ah Obirin yi, dakun, jọọ o, dakun, jọọ o Ye gbọ t'ẹlẹgan Ye gbọ t'ẹlẹgan Ye gbọ t'ẹlẹgan Fura si ara
Writer(s): Ashimi Ibrahim Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out