Lyrics

Ebenezeri wa re oo Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de Ka'ma jo o, kayo, ka fogo folu Ninu irinkerido mi laye, eh Íwọ lo ba mi sé Alubarika lo wa mi ri Emi kọ, isẹ ọlọrun ni Ewu gbógbó ti mo la kọja Ki ma yí se agbara mi Atinuda ti mo di, lo njẹ ki dupe ore Ebenezeri wa re oo Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de (nibi ti ẹ ran wa lọwọ de) Ka'ma jo o, k'ayọ, ka fogo folu (Ebenezeri) Ebenezeri wa re oo Ema ma se ẹse Kima nse nipa agbara Oluwa loni imo ati oye (oluwa lo ni iranlọwọ) Ogo t'aye rí ti wọn polongo Irẹ lo ba wa se Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kọ (oh my God) Ẹse ibi t'ẹti bẹrẹ Ẹse ibi t'ẹba de Adupẹ Oluwa Ibi t'ẹmu wa lọ Tori, ibasepe oluwa koti wa niti wa ooo Nibo la ba jasi Amo ni sẹ yin, adupẹ at'ọpẹ da Tori wipe, awọn kan gbẹkẹlé kẹkẹ Awọn kan gbẹkẹlé ẹṣin Awa ta gbekele ooo Ibi tomu wa de, ibi ogo ni Lase wi pe Orin halleluya Orin hosana ooo Orin Ebenezer Hosana lo gbẹ'nu wa kan (ẹkorin ebenezeri o) Ebenezeri wa re oo Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de (ibi tẹ ran wa lọwọ de) Ka'ma jo o k'ayọ ka fogo folu (ẹsẹ ibi te ti beere) Ebenezeri wa re oo (ibi ti ẹ ba wa de) Ema ma se ẹse Kima nse nipa agbara Oluwa loni ìmọ ati oye (Oluwa lo ni iranlọwọ) Ogo ti aye rí ti wọn polongo Irẹ lo ba wa ṣe Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kan Oh-oh-oh-oh, ka panu pọ ka'dupẹ (ka'dupẹ) Oh-oh-oh-oh, ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (oh-oh-oh) Oh oh oh oh, a pànu po ka'dupẹ Oh-oh-oh-oh, Ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa Tori pe Àgbọn igbẹ ibunkun aidiyẹle To fi fun wa ah ah ah La ṣe ndupe (ẹ ho iho ayọ si oluwa) Oh-oh-oh-oh, ka panu pọ ka'dupẹ (oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh) Oh-oh-oh-oh, ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (ọkan mi yin oluwa logo) Oh oh oh oh, a pànu po ka'dupẹ (mo mu ore wa sọdọ rẹ, mo panu pọ, adupẹ) Oh-oh-oh-oh, a Ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (tori abu bu tan ore rẹ) Aidiyẹle To fi fun wa ah ah ah La ṣe ndupe Moni, agbón igbẹ ibunkun aidiyẹle To fi fun wa ah ah ah La ṣe ndupe Gbogbo aye mi sọrọ ogo rẹ Tori abukun tan ore To se fun mi, oh oh ah eh La se ndupé Ebenezeri wa re oo Nibi ti e ran wa lowo de Ka'ma jo o kayo ka fogo folu Ebenezeri wa re oo Ema ma se ese Kima nse nipa agbara Oluwa loni imo ati oye Ogo t'aye ri ti wọn polongo Irẹ lo ba wa ṣe Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kan
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Get up to 2 months free of Apple Music
instagramSharePathic_arrow_out