Lyrics

Oba ni Jesu eh Oba ni Jesu oh oh Oba ni Jesu ye eh Oba ni Jesu Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu Mo ti sonu si'nu igbekun ese mi S'afonifoji iku, ati gbagbe mi A ti ro mi pin, pe ko si ireti fun mi mo Tori mo j'ebi, gbogbo esun ta kan mo mi Mo ti sonu si'nu igbekun ese mi S'afonifoji iku, ati gbagbe mi A ti ro mi pin, pe ko si ireti fun mi mo Tori mo j'ebi, gbogbo esun ta kan mo mi Sugbon ide mi ja mo d'ominira, lati'gba, mo ti gba Jesu A ti ra mi pada, a ti san gbese mi, ni pa eje Jesu Jesus, Yours is the victory (Sing halleluyah o) Halleluyah, praise the one who sets me free Halleluyah, death has lost its grip on me You have broken every chain There's salvation in Your name Jesus Christ, my living hope Oba ni Jesu eh Oba ni Jesu oh oh Oba ni Jesu ye eh Oba ni Jesu Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu Every situation surrenders to His name No condition is above His jurisdiction At the snap of His fingers, everything lost must be restored Afterall, na only Him be God I'm walking in power and victory Tori mo ti mo Jesu I'm sanctified, I get immunity Tori moti gba Jesu Jesus, Yours is the victory (Sing halleluyah o) Halleluyah, praise the one who sets me free Halleluyah, death has lost its grip on me You have broken every chain There's salvation in Your name Jesus Christ, my living hope Say halleluyah Halleluyah, praise the one who sets me free Halleluyah, death has lost its grip on me You have broken every chain There's salvation in Your name Jesus Christ, my living hope 'Cause you have broken every chain There's salvation in Your name (Jesus Christ, my living hope) Tori o ti yo mi kuro 'nu igbekun, o san gbese ese ti mo je (Jesus, Yours is the victory) 'Cause you have broken every chain There's salvation in Your name (Jesus Christ, my living hope) Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu ye eh Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Ooh Oba ni Jesu Gbogbo aye, gbe Jesu ga Angel', e wole fun Angel', e wole fun E mu ade Oba Re wa Se l'Oba, a-a-a-a l'Oba A-a-a-a l'Oba A-a-a-a l'Oba A-a-a-a l'Oba A-a-a-a l'Oba A-a-a-a l'Oba Se l'Oba, awon Oba Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu ye eh Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Ooh Oba ni Jesu Gbogbo aye, gbe Jesu ga Angeli, e wole fun E mu ade Oba Re wa Se l'Oba, awon Oba (Gbogbo aye o, yeeeh) Gbogbo aye, gbe Jesu ga Angeli, e wole fun E mu ade Oba Re wa Se l'Oba, awon Oba E se l'Oba eyin Martyr Ti npe ni pepe Re E ki Eni t'o gba yin la Se l'Oba awon oba Gbogbo aye, gbe Jesu ga Angeli, e wole fun E mu ade Oba Re wa Se l'Oba, awon Oba Oya Oba Oba Oba Oba aye o Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu Tor'oun ni Arugbo Ojo Wo, so'pe, eru Oba ni mo ba Oba to, eru Oba ni mo ba, Oba to Arugbo Ojo, iwo l'aseda, l'aweda, l'ameda o (Arugbo Ojo) Iwo loni ogo, loni iyin, loni ola (Arugbo Ojo) Mo tun wa ni, mo ni M'ba m'oriki re, m'ba korin lai dake M'ba fi'jo yin bi okoto Jesu Ma jo roin roin roin, arugbo (Arugbo Ojo) Oba, Oba, Oba ni o Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Ooh Oba ni Jesu Oya so pe Mimo, mimo, mimo! Olodumare Ni kutukutu n'iwo y'o gbo orin wa Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo Ologo meta, lae Olubukun Oba ni, Oba ni, Oba ni o Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu Won n'korin kan simi leti, won ni'pe Si O Olutunu Orun Fun ore at'agbara Re A nko, A nko, A nko, Aleluya Si O, ife eni t'O wa Ninu Majemu Olorun A nko, A nko, A nko, Aleluya Oba ni, Oba ni, Oba ni o Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu Oba aiku, airi, Orisun Ogbon To wa n'nu imole, t'oju kole wo Olubukun julo, Ologo julo Alagbara, Olu-segun, 'Wo la yin Oba ni, Oba ni, Oba ni, Oba ni o Oba ni Jesu Oba ni Jesu Oba ni Jesu Ooh Oba ni Jesu He is the King, of Kings He is the Lord, of Lords His name is Jesus, Jesus, Jesus, Jesus J-E-S-U-S He is the King Oba ni, Oba ni, Oba ni o Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu (Oba awon Oba) Oba ni Jesu (Kabiyesi Re) Oba ni Jesu (Oba awon Oba) Oba ni Jesu (Oba awon Oba) Ooh Oba ni Jesu Tori ide mi ja mo d'ominira, lati'gba (Mo ti mo Jesu) Ide mi ja mo d'ominira, lati'gba (Mo ti gba Jesu) How many of you know Dunsin Oyekan o? Are you ready? Dunsin lo soro kan ko ma de fi puro, oso wi pe Generations, after generations Keep praising You, yet no word sums you up Generations, after generations They keep praising You, yet no word sums up And I asked the Lord, "What name fits You? And He said, "Yah", "Yah" Generations, after generations They keep praising You, yet no word sums up And I asked the Lord, "What name fits You? And He said, "Yah", "Yah" Yah, the Hallowed One Jesu Kristi, Yah, the Holy One Yahweh, the King of Zion Yah, the Hallowed One Jesu Kristi, Yah, the Holy One Yahweh, the King of Zion Tori boda mi Nathaniel Bassey, ni mo se nso pe, ye-e-e-eh Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Sing Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Sing Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Hallelujah, Amen Sing Hallelujah, Amen Mommy, Daddy, wo se Olorun l'aye re o T'e ba wo'se Olorun l'aye re o Wa wa ri wipe, wa mo pe, there is nothing He cannot do There is no mountain He cannot move There is no prayer He cannot answer There is no problem He cannot solve If He has said it, then He will do it If He has said it, then He will do it He has a record of keeping His word He's not about to stop doing it now Oya sope, Olorun Agbaye, You're Mighty oh Olorun Agbal'aye, You're Mighty oh Shebi wo lo f'oju Orun s'aso bora Shebi wo le f'oju Orun s'aso bora Olorun Agbaye, You're Mighty oh Oba ni Jesu eh eh, Oba ni Jesu Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Oba ni Jesu (Oba ni o) Ooh Oba ni Jesu
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out