Lyrics

Ah ah Ah MO dupe temi o To o ba seleyi talolemu o si Opo Egbe mi lo wo so jade Nile to ku si igboro Oluwa ah ah Oluwa ah ah Mo dupe temi To o ba seyi koseni tolemu o si Mo dupe temi o To o ba damisi ta lofe mu o Opo Egbe mi lo woso jade nile to ku si igboro Opo Egbe mi lo woso jade nile Aso nwon fi dawon mo ni ta O je ki aye mu Awon eniyan lo si Ibi iboji mi O je won o fi irun mi dami mo ni mortuary O je won o fi Aso dami mo Nitori jijade ati wiwole mi Owo re lowa o Nitori jije mimu mi Jesu Owo re lo wa o Bi mo se nlo ti mo n bo nigbagbogbo Olorun Owo re lo wa Oluwa ah ah Oluwa ah ah Oluwa ah ah
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out