Lyrics

Mo mo Ah ah ah, ah ah ah, ah ah ahhh (xcluso, the sound maker) Eh eh eh, eh eh eh, eh eh ehhh Motun ti de gege bi mo se n de (xcluso on the beat) Mo ti be olodumare ki baba ba mi se Mo lo irinajo, awon ota won o fe ki n de Sugbon ifa olokun baba ti ba mi se Mo mo pe orin ti mo fe ko yii Won ma gb'ogun Sugbon eni logo, ko le salailogun Eni n lo lasan won mu okuta gan won tun so fun Mo mo pe ifa a ba mi segun Bi erin ba ji erin a ki olu'gbo Bi efon ba'ji efon a ki olu odan Erin to ba ji ti ko ba k'olu'gbo Beeni efon to ba ji ti ko ba k'olu odan Awon mejeji won fi ara won fi kasa Mi ba tija wa beeni mi ba tere wa Ti won ba ni isoro awa naa na ma saba Awon to n fi oruko mii gba yin le gan won ni ifa Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo Bi'ro ba lo fun ogun odun Ooto ma ba lojo kan Ifa tide Ifa wa kayejo E ma je ka tako ara wa pelu oro siso Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo Bi'ro ba lo fun ogun odun Ooto ma ba lojo kan Ifa tide Ifa wa kayejo E ma je ka tako ara wa pelu oro siso Ebe ni mo be apari inu mi Ko ma se je ki n rogun elenini (xcluso, the soundmaker) Ki awon kan ko ma se je ipin mi (xcluso on the beat) Ki omo araye ki won ma se damu mi Ire ni ki n ma ri, baba ma je n ri ibi (xcluso on the beat) Oju to ma ri ire ko le se alai ri ibi Ti won ba wa fi ifa buru baba ma je won o ri mi Baba gbo adura mi ko to su mi Ope fun olorun oo, oba toto Iyin ye e o, odumare Ogo ye oo orunmila Iyin ye oo asiwaju rere Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo Bi'ro ba lo fun ogun odun Ooto ma ba lojo kan Ifa tide Ifa wa kayejo E ma je ka tako ara wa pelu oro siso (oh) Ope fun olorun oo, oba toto (xcluso the sound maker) Iyin ye e o, odumare (eh eh) Ogo ye oo orunmila (xcluso on the beat) Iyin ye oo asiwaju rere
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out