Lyrics

E se Aye ope yo E se toripe aye ope yo E se Aye ope yo o Emi awon woli o Aye ope pada yo Gbogbo ale ta sun ta ji, aye ope kan ni Gbogbo igba ta ba sun lale, Ta o ranti lati Gbadura, e o gba ki ile wo pa wa lat'oju orun wa saye Aimoye igba ta ma ji, ta ma ma sare pe a ti late Otun d'abo bo wa o O f'aye gba satani lati yo ayo isegun lori aye wa Aye ope pada yo L'ati ile loti mu wa o mu wa joko pelu awon omo alade O f'aye gba wa laarin awon omo alade ilu wa A wa n'soro nibi giga Mo ki o toripe aye ope yo o Emi awon woli o Aye ope pada yo Melo leebu awon eyan lara wa, to gbon danu Pelu eri Melo ni awa to ti rope, Ohun rere o le ti Inu wa jade, To funrugbin ohun rere sinu wa to Tun jeyo Mo ki o toripe aye ope yo o After all we've been through Aye ope pada yo Igba kan ri won da'so fun o ko to di pe awon Omo to bi ri aso wo ni o Igba kan ri won da'so fun o ko to di pe Awon Omo to bi ninu re r'aso bo ihoho won Igba kan ri o pelu awon ton gbe kiri Lati ma toro Owo loju titi ese oloore toripe Aye ope pada yo Ah Aye ope yo O se aye ope yo O se Aye ope yo o Emi awon woli o Aye ope pada yo Igba ti o si nkankan se pe aye ope le yo Igba ti gbogbo ohun gbogbo doju ru se pe aye Ope tun le yo Ki la o ni dupe fun nigbati aye ope ti yo o After all we've been through Aye ope pada yo Igba kan ri won pe o l'agan o Sugbon lowolowo o pada gbomo jo Igba kan ri won sa fun o lawujo awon eyan gidi Sugbon lowolowo o ti joko pelu awon olola Igba kan ri oo won ti write e off pe ohun rere o le Tinu re Jade wa, won ti write e off pe ohun rere o Le tinu re jade wa Sugbon emi Inu awon woli, Agbanilagbatan Agbani ma gbowo, Arugbo ojo jojo ninu eni to Fun ojo loju lati ma yo Ninu re ni ojo tin je ojo o, ojo to yo ninu re lo Jo Oju ton riran ninu okunkun birimu birimu Eni nla ton se ohun nla Eni nla ton se ohun ari tokasi Eyan a ma gbe oyun sinu, fun gbogbo osu mesan, iwo na ni abo won Eni aye de oyun mo ninu fun odun meji, Meeta, meerin, maarun, meefa logan to ba o pade O tu won sile lai gba ohunkohun rara Emi awon woli o O se o, toripe aye ope pada yo Aimoye oloyun to yo ninu ewu Aimoye trailer to subu Lu motor O je a si lara won A o gbe ounje pari, a le mai si nibi toye Ka wa Sugbon a dupe ibi te ba wa de Kinihun eya Judah aye ope pada yo Ohun gbogbo lo se fun mi Ohun gbogbo lo se fun mi Ki lo ti se fun mi ko si o Ohun gbogbo lo se fun mi O fun mi lomo bi o se o O fun mi loko fe o se o Iwo to gbe mi jade lati inu ira To fo mi laso mo Iwo to pin okun pupa niya lai se pe Omi ya lu Awon omo isreali lojo yen Bawo lo se se, iwo ni o kabiyesi olola, iwo na ni Ohun gbogbo lo se fun mi Ohun gbogbo lo se fun mi Ki lo ti se fun mi ko si o Ohun gbogbo lo se fun mi Gbogbo ojo lon d'abo bo mi lon yo mi ninu ewu Lara ohun to se fun mi ti mi o le so Ni emi ti mon Mi sinu to o gba lowo mi Lara ohun to se fun mi ti mi o le so tan ni oju Iriran, Ese ton rin, owo ton sise, Eti ton gboran, Speaker to soro jade ninu mi o be o Ohun gbogbo ma lo se ninu ohun gbogbo Aimoye ijakadi lile to ja lori oro mi loru moju Iwo lo se, iwo lo je ohun gbogbo ninu ohun Gbogbo, Atobi tan o, atoba tan, a to Baba ma pe Enikeni ni Baba Iwo ni o o o Oro tin gbe'nu Omo eniyan f'ohun Oro ton gbe inu ikoko tu asiri won ni gbangba Oju to ri okunkun ninu okunkun o Oju to la okunkun loju ninu okunkun birimu Birimu, iwo na ni Baba mi o o o A dun f'oro lo, a to ba soro, a to f'ise ogun ran, A to Baba ma pe Enikeni ni Baba, Aridunnu mi nigba Ti ibanuje de, Owo ton gba ibi kuro loju ona Wa, iwo ma ni, iwo ma ni o Iwo ni, iwo ma ni o Iwo ni Baba mi o, iwo ni ore mi Bawo lo se se Ti igi fi koja lo sinu omi to magnet irin wa sori Omi, Aake to jabo sinu omi lojo yen igi lo Fi gbe jade, owo airi re lon sise agbara o Owo airi re lo se wonder lojo yen Iwo ni, iwo ma ni Bawo lo se se Obinrin onisun eje laarin egbegberun Eniyan ton Lon, ase jade Lara re Logan lo mo o O koja lo sorisun isun eje odun mejila, loba gbe Lesekese o, Awon oni dokita ati babalawo won ti Gba, gbogbo eyan ti gba, Woli ika ti gba, real woli Ti gba, Sugbon Logan ti o ba o pade lo rowo Agabara Bawo lo se se Iwo ni, iwo lo ye Odi Jericho, o subu pelu ariwo leekan sooso Bawo lo se se Awon omo isreali rin l'aginju fun odidi Ogoji Odun, bata won o je, aso won o gbo Iwo ni asiri ton so won di tuntun lojojumo Bawo lo se se o kabiyesi olola Bawo lo se se oni wonder ton gbe wonder mi o Iyanu ton ya aye lenu, bawo lo se se Oni wonder oni wonder o se o Emimimo bawo lo se se Ti iyo kekere fi trace arin omi, Ko disappear to fi De orisun isale odo mara, O so di didun, o so di Didun, o so odo mara di didun Oni wonder oni wonder o se Jesu oni wonder o se o Jesu oni wonder o se o Jesu oni wonder o seun Eru ton d'eru b'eru o Eru t'eru ri to sa t'eru o le ba o Erujeje ton d'eru b'eru o Eru re ba mi olodu to mo gbogbo are patapata Ina loju, ina lenu Gbogbo ara kikida ase Ibi to ba de l'ase duro si Ibi to ba si iyanu o ki le sele o Ninu re ni aragba yamuyamu iyanu ngbe ti o Le Tan, orisun iyanu, orisun ara, inu re ni Oni wonder oni wonder o se Jesu oni wonder o se o Jesu oni wonder o se o Jesu oni wonder o se o Iwo l'ariwo to ta laarin awon egungun gbigbe Iwo lo so egungun gbigbe di aye ti ori wa orun Ri Ti orun wa ara won ri ti won o miss ara won Iwo l'asiri ton gba yitiyiti ninu osumare Asiri ta wa ta o ri, iwo na ni E ru, oba eru, oba eru Eru re to ba o E ru, oba eru, oba eru Eru re to ba o Eru ton d'eru b'eru Eru t'eru o le ba o Erujeje t'eru o le ba o Eru re to ba o E ru, oba eru, oba eru Eru re to ba o Eni ti gbogbo aye binu si, wa ma yonu si Eru ni o Eni ti gbogbo aye pada leyin re, wa ma fa mora Eru ni o Eni ti gbogbo aye nda lebi, wa ma da won lare Eru ni o E ru Eru re to mi ba o E ru, oba eru, oba eru Eru re to ba o E ru, oba eru, oba eru Eru re to ba o Gbogbo eda to ti write off, wa ma si new Chapter fun won Eru re to mi ba o E ru, oba eru Eru re to mi ba o
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out